Home orisiirisii Èèyàn mẹ́ta ti kú lẹ́yìn tí kọ̀ǹténà j’ábọ́ lé ọkọ̀.
orisiirisii - Orisirisi - July 24, 2019

Èèyàn mẹ́ta ti kú lẹ́yìn tí kọ̀ǹténà j’ábọ́ lé ọkọ̀.

Ijamba oko ti o sele ni ojo Tuesday ni ilu Akinhale, Ewekoro ni titi Lagos-Abeokuta Expressway, ni ipinle Ogun, ti gba emi eeyan meta o si pa awon elomiran lara.

Ijamba oko naa sele laaarin Iveco truck, ti nomba re je AAA 912 XK, naa waye leyin ti diriba oko naa padanu wiili oko naa, ti o si fa ki kontena naa jabo lara oko naa ti o si wonu igbo lo.

Agbenuso Traffic Compliance and Enforcement Agency, Babatunde Akinbiyi, lo fi idi eri isele naa mule, o ni won ti gbe oku awon eni ti isele naa se ti lo si motuari Ifo General Hospital, won si ti gbe awon meji ti won sese lo si ile iwosan ni ifo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…