Home orisiirisii Arákùnrin ọmọ ọdún márùndínláàádọ́rin ti kú ni ilé ẹjọ́ ní Edo.
orisiirisii - Orisirisi - July 24, 2019

Arákùnrin ọmọ ọdún márùndínláàádọ́rin ti kú ni ilé ẹjọ́ ní Edo.

Arakunrin omo odun marundinlaaadota, Moses Airhiagbonkpa, ti subu o si ti ku ni aaro yii ninu ogba ile ejo ni ipinle Edo.

Gege bi iroyin se so,Airhiagbonkpa wa ni ilẹ̀ kewa ni ile ile-ejo giga pelu awon egbe Ugiekhue lati gba deeti tuntun fun ejo ti o ni se pelu agbegbe naa.

Itọ n gbon arakunrin naa, o si fe lo yara igbonse. Bi o se si ilekun ti o ni ki oun wole, lo jabo si isale. Nigba to ya ni won ri pe Airhiagbonkpa ja si aaye gbangba nibi ti egbe ile naa wa tele. Ile ejo naa n se awon atunse, lara nnkan ti won si n tunse ni egbe naa. Awon ti n sise lowo yo egbe naa kuro pelu ero pe won ma tete fi imii sibe pada.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…