Home iroyin America ti fi ìhámọ́ sí orí físà fún àwọn olóṣèlú Nàìjíríà.
iroyin - òpómúléró - orisiirisii - Orisirisi - July 24, 2019

America ti fi ìhámọ́ sí orí físà fún àwọn olóṣèlú Nàìjíríà.

Orile-ede America ti kede ni ojo Tuesday pe won ti fi ihamo si oti fisa fun awon oloselu Naijiria ti won lero pe won le da idibo 2019 ru.

Won o darulo ninu ikede naa, amo awon ti oro naa bawi ni awon ti won lowo ninu iwa ipanle ninu idibo, madaru idibo ati awon iwa ibaje orisirisi ninu idibo, ki won to bere ibo, ninu ibo ati leyin ibo 2019.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…