Home iroyin Akẹ́kọ̀ọ́ AAU ti kú lẹ́yìn tí ó kúrò ní àgó EFCC.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - July 24, 2019

Akẹ́kọ̀ọ́ AAU ti kú lẹ́yìn tí ó kúrò ní àgó EFCC.

Arakunrin omo odun mejilelogun ti o je akekoo ile iwe Ambrose Alli University ti ku leyin ti o lo osu meji ninu ago EFCC, ki won to fi sile.

Won mu Austin Isiah fun ese ti ko “mowo mese”. Won mu sile fun osu meji, ki won to fi sile, leyin ti o saare ni ago won, gege bi awon ore re se so lori Facebook.

Leyin ti won fi sile, o ku ni ojo Monday July 22, latari aare naa.

Awon ore re ti n s’ofo re lori Facebook, won si n ba EFFC wi pe ese “aimowo mese” ni won mu fun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…