Home iroyin Wọ́n ti lọ gbé òkú Precious Owolabi ní motuari.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - July 23, 2019

Wọ́n ti lọ gbé òkú Precious Owolabi ní motuari.

Adari NYSC,Brig-Gen.Shuaibu Ibrahim ti lo b’owo keyin fun Ogbeni Precious Owolabi, agunbaniro ti n sin ile baba re ni Channels Tv ti Abuja.

Ibrahim se ayewo oku naa ki won to gbe kuro ni National Hospital Abuja ni ojo Tuesday, lo si ile.

Ota ibon lo gba Owolabi ni ojo Monday nigba ti awon olopaa ati Islamic Movement members ti awon eeyan mo si Shi’ites jo n bara won fa wahala.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…