Home iroyin Wọ́n ti ṣe ìsìnkú Funke Olakunrin.
iroyin - òpómúléró - orisiirisii - Orisirisi - July 23, 2019

Wọ́n ti ṣe ìsìnkú Funke Olakunrin.

Won ti se isinku Oloogbe Funke Olakunrin, omo olori egbe Afenifere, Pa Reuben Fasoranti, ni St. David’s Anglican Church Ijomu, ni Akure, ipinle Ondo ni ojo Monday July 22.

Awon ti won wa ni ibi isinku naa ni Gomina ipinle Ondo, Arakunrin Oluwarotimi Akeredolu, ati awon elegbe re lati Ogun, Eko, Ekiti ati Oyo. Omo Oba Dapo Abiodun; Ogbeni. Babajide Sanwo-Olu ; Dr. Kayode Fayemi; Oluseyi Abiodun Makinde, Gomina ipinle Onda ana, Dr. Olusegun Mimiko ati awon ijoye miiran.

Awon adigunjale lo yinbo pa Olakunrin ni tiyi Benin-Ore ni ojo Friday July 12.

O je omo odun mejidinlogota, o fi baba re sile, oko re Idowu Olakunrin, awon omo ati omo-omo. Ki olorun te emi re si afefe ire.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…