Home iroyin Wọ́n ti ṣá ọmọ ọdún mẹ́jọ pa.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - July 23, 2019

Wọ́n ti ṣá ọmọ ọdún mẹ́jọ pa.

Won ti ri oku omo odun mejo ti n je Aisha Sanni, ti arabinrin kan ji gbe ni ose meji seyin ni Tudunwada ni ipinle Kano.

Gege bi iroyin se so, arabinrin kan ti o da aso boju ni o gbe Aisha gbe nigba ti oun ati awon re kuro ni ile iwe Islamiyya. Arabinrin ti o ji Aisha gbe ayi egbe re pe awon obi re leyin ose kan, ti won si n bere fun milionu naira lona igba ki won to fi omo won sile.

Awon ajinigbe naa ni ki won gbe owo naa fun iya Aisha, ki o si gbe wa fun awon. O se ni laaanu, pe leyin ose meji ti awon olopaa ti se iwadii, ti won si ti wa omo naa, won ri oku Aisha ni ojo Monday. Awon ajinigbe naa ti sa pa.

Awon obi re ti gbe oku re lati lo si in.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…