Ọmọ Gomina Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ àná, Abiola Ajimobi ti jáde ilé ìwé gíga.
Gomina ipinle Oyo ana, Abiola Ajimobi ati iyawo re, Florence Ajimobi n se ajoyo lowo leyin ti okan lara omo won obinrin, Ajijola, jade lati University of Warwick ni United w. O gbe iwe eri Bachelor of Art in History and Sociology.
A ki won ku ori ire.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…