Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Nigeria yóò gba milionu nara lona 714 fún ipò kẹta ni AFCON 2019.

Nigeria yóò gba milionu nara lona 714 fún ipò kẹta ni AFCON 2019.

Awon Super Eagles Nigeria yoo gba milionu naira lona 714(714milkionu naira) to je milionu dollar meji(2million dollars) lowo Confederation of African Football (CAF)fun pe won kopa ninu 2019 Africa Cup of Nations (AFCON) ati pe won gba ipo keta.

Nigeria gba 1-0 pelu Tunisia, ti o fun won ni ipo keta, ti won si gba ebun bronze, eyi ni igba kejo ti Nigeria ma gba ipo naa ni AFCON.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…