Home orisiirisii Ènìyàn mẹ́jọ ti kú sínú táǹkì omi.
orisiirisii - Orisirisi - July 23, 2019

Ènìyàn mẹ́jọ ti kú sínú táǹkì omi.

Awon olopaa ioinle Enugu ti so pe eeyan mejo ni won ti ku sinu tanki omi ti o wa labe ile ni Enugu.

Agbenuso olopaa ipinle naa, PRO, Ebere Amaraizu lo fi idi eri isele naa mule. Amaraizu to je Superintendent Police (SP) ni isele naa waye ni ile kan mi ni Igogoro ni Igboeze North Local Government Area ti ipinle naa ni ojo Monday, July 22, 2019.

Gege bi o se so “arakunrin kan ti won ko tii damo, to n sise ni ile naa, lo si inu tanki naa lati fa omi jade nibe, amo o ha mo inu re, ko ribi jade.

“Leyin ti won duro ko pada de ti ko si pada, ni won bere si ni lo si inu ibe loyokookan, bi gbogbo won se ha sibe niyen.”

Amaraizu ni awon ti ba won kedun ati awon olopaa ni won ko won jade ti won si gbe won lo si ile iwosan General Hospital Ogurute, ti dokita to wa lori ijokoo ni won ti ku. Won si ti gbe oku won lo si motuari.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…