Home orisiirisii Wọ́n ti dáná sun olè.
orisiirisii - Orisirisi - July 22, 2019

Wọ́n ti dáná sun olè.

Ni opin ose ti o koja, awon agbajo eeyan na ole kan ti won fura si won si dana sun un ni Badagry Expressway ni Eko.

Gege bi iroyin se so, isele naa waye ni abe biriji International Trade Fair ni Ojo, ni akoko ti awon oloja n lo si ile. A gbo pe eni ti won fura si naa je okan lara awon omo egbe meta ti n da agbegbe naa laamu.

A gbo pe won ri arákùnrin naa ati awon meji to ku ti won n rin gberegbere laaarin Trade fair ati Mile 2, ti o mu ifura dani pe ole inu sukere oko ni won. Won ni awon ole naa gbe okoda meta wa ti won fi ti si titi ni egbe Abule-Osun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…