Ushbebe pe Mercy ati Tasha ní onípanṣágà tí ó gbajúmò.
Nigba ti Ushbebe n se efe ninu apejopo Akpororo ni ile ana ni Eko, o pe awon ara ile Big Brother, Tacha ati Mercy ni onipansaga to gbajumo.
O salaye ifi yi okunrin fi nilo “geesi ati iparamo”, Ushbebe pe awon ara ile Big Brother ni ‘onipansaga’o si pe Tacha ni alailekoo.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…