Home iroyin Àwọn Fulani tí ń sin màlúù tún ti gbé ìṣe wọn dé.

Àwọn Fulani tí ń sin màlúù tún ti gbé ìṣe wọn dé.

Awon arabinrin meta ti n rin irin ajo lati Eko si Yenogoa, ipinle Bayelsa, ti bo si owo awon ajinigbe ti won fura si pe won je Fulani ti n sin màlúù ni ojo Sunday.

Awon obinrin naa ni won pe ni Okuboere, Seifefa ati Amara, won ni isele naa sele ni ago mejila osan ni agbegbe awon Hausa-Fulani ni Okada, ipinle Edo. Ana okan lara awon ti won ji gbe Princess Grace, ni;

“ Awon ana mi, ipinle Bayelsa, Okuboere, Seiyefa ati ore won Amara omo Abia ti bo si owo awon ajinigbe ti won fura si pe won je Fulani ti n sin maluu ni titi Okada ni ipinle Edo ni ago mejila osan.

“ Won n wa oko bo lati Eko lo si Yenagoa pelu awon omo meji ninu oko.

“ Won ni awon odaran ti n sin maluu naa yin ibon fun won lati iwaju, bi won se n gbiylati fi eyin salo ni won yo si won leyin. Won je omo ile Sagbama LGA ni Bayelsa, ore won si je omo Arochukwu lati ipinle Abia.

“Awon omo naa omo odun mejila ati merin ni won fi sile ninu oko ninu igbo. Ni ale ana, okan lara won pe mi pe ki n pe awon obi awon, pe won n beere fun milionu naira ogbon.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…