Home orisiirisii Arákùnrin ọmọ ọdún mọ́kàndínlọ́gbọ̀n ti fi ipá bá ọmọ ọdún márùndínlógún lòpọ̀.
orisiirisii - Orisirisi - July 22, 2019

Arákùnrin ọmọ ọdún mọ́kàndínlọ́gbọ̀n ti fi ipá bá ọmọ ọdún márùndínlógún lòpọ̀.

Olopaa ti gbe arakunrin omo odun mokandinlogbon ti n je Ogbeni Uzor, fun esun pe o fi ipa ba omo odun marundinlogun lopo ni Asaba, ipinle Delta ni ana July 21.

Ajafetoo, Harrison Gwamnishu lo gbe isele naa si ori afefe, o ni omo naa n gbe ni ile oun ti eni ti a fi esun kan je ara ile oun. Arakunrin naa hu buruku yii nitoei oun o si ni ile.

Alagbafo kan ti o je ara ile mi fi ipa ba omo odun marundinlogun lopo ninu ile mi.

Ni osan oni, mo kuro ni Asaba lo si Enugu fun ipade pajawiri lai mo pe ko pe ki ni oku eeyan lorun. Ninu ile mi, okunrin fi ipa ba omo mi lopo.

Won ti gbe omo naa lo si ile iwosan, eni ti won fura si naa wa ni ago olopaa, o si ma to fi oju ba ile ejo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…