Home Entertainment Orí Facebook ni mo ti pàdé ọkọ mí – Simi.

Orí Facebook ni mo ti pàdé ọkọ mí – Simi.

Gbajumo akorin omo Naijiria, Simi ti o je aya gbajumo akorin Adekunle Gold, ti salaye ninu iforowanilenwo bi oun se pade oko oun, bi o tile je pe bonkele ni won fi ibasepo won se.

Ninu ifoworowanilenuwo ti o ni pelu Ndani tv ni o ti salaye pe ori Facebook ni oun ti pade Adekunle Gold, ati igba akoko ti awon ma pade ni igba ti oun dari ariya kan ni Eko.

O si salaye pe nigba ti oun koko pade oko oun, oun o mo pe olorin rin, ayaworan ni oun mo o si. Ko to di pe awon di ore, awon bere si ni se wolewode titi awon fi se igbeyawo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…