Home Entertainment Kò wùnmí láti fi oyún mí pamọ́ – Wunmi Toriola.

Kò wùnmí láti fi oyún mí pamọ́ – Wunmi Toriola.

Gbajumo osere onitiata Yoruba, Wunmi Toriola ti kilo fun awon ti n gba nimoran pe ki o ye gbe oyun re sita fun araye ri pe ki won fi oun sile, pe won n fa nnkan odi si ori paagi oun.

Gege bi o se so, o ni oun fe ki awon eeyan bọwọ fun ipinnu oun gege bi oun se ma n bowo fun awon ti n gbe ni ile olorogun ti won ko si gbe sita. O si ti so fun won pe ki won ye fi ipa fa iru igbesiaye won le elomiran lowo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…