Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Odion Ighalo ti fẹ̀yìntì.
ERÉ ÌDÁRAYÁ - orisiirisii - Orisirisi - July 19, 2019

Odion Ighalo ti fẹ̀yìntì.

Agbaboolu omo ile Naijiria, Odion Ighalo ti fẹ̀yìntì ninu boolu oke okun fun Super Eagles, yoo si ma se ikede laipe, leyin ijade aseyori ni 2019 African Cup of Nations.

Agbaboolu naa lo gba gba goolu fun Naijiria ti a fi de ipo keta, leyin ti Nigeria ati Tunisia pade ni ojo Wednesday fun ipi keta ni AFCON.

Ighalo ati koosi awon Suoer Eagles jo gba pe ko ni kede ifeyinti re titi won ma fi gba boolh ipo keta ti won gba pelu Tunisia.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…