Home orisiirisii Mo fi ipá bá ọmọ mí lòpọ̀ ki n lè mọ̀ bóyá wọ́n ti já ìbálé rẹ̀ – Arakunrin.
orisiirisii - Orisirisi - July 19, 2019

Mo fi ipá bá ọmọ mí lòpọ̀ ki n lè mọ̀ bóyá wọ́n ti já ìbálé rẹ̀ – Arakunrin.

Arakunrin kan ti n je Wasiu Orilonise, omo odun metadinlogoji, ti n se sise oluso, ti jewo pe oun fi ipa ba omo oun odun marundinlogun lopo, leyin ti won gbe lo si ile ejo ti Oyo Sate Magistrates’ Court ni Ibadan.

Arakunrin naa si n be ile ejo pe oun fe se ayewo boya won o ti ja ibale omo oun nitori oun fe daabo re.

Arakunrin na so fun Chief Magistrate, Ogbeni Taiwo Olaniran pe iyawo oun ti ku lodun die seyin. Nigba ti won bere idi to fi se nnkan to se, o ni lati igba ti iyawo oun ti ku, oun ni oun toju omo naa ati awon iyoku re, amo oun pinu lati mo boyawon ko ti ja ibale omo oun ni December 2018 ni ile awon ni ilu Omo, Agbofieti, Ibadan. Nigba ti oun ri pe won ko tii ja ibale re, oun bere sini ba ni ibasepo pni aaro ki o to lo si ile iwe ati ni ale.

Won ti sun ejo naa si iwajutiti di July 30, 2019, amo ile eje o gba ebe Orilonise, nitori naa, won fi si ewon Agodi, titi digba ti pwon ma fi gbo imoran láti odo awon adari.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…