Home orisiirisii Èèyàn ọgọ́ta tí jàre ikú lẹ́yìn tí ilé wó.
orisiirisii - Orisirisi - July 19, 2019

Èèyàn ọgọ́ta tí jàre ikú lẹ́yìn tí ilé wó.

Eeyan ogota ti jare iku ni Abakaliki, ipinle Ebonyi ni ale ana leyin ti apa kan ni Metro View Hotel.

Gege bi manija hotel naa, Austine Orji se so, o ni awon ti sakiyesi ila lara ile naa, pe awon si ti bere si ni tun re. Orji ni enu ise naa ni awon wa ti ile naa fi wo.

O ni, enikeni o k, nitori awon ti won gba yara ninu ile itura naa wa ni ita fun ipade(seminar).

Leyin isele n, Abakaliki Caputal Territory Development Authourity ti ti ile itura oni yara merindinlogbon pa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…