Home orisiirisii Bàbá ọdún mọ́kànléláàádọ́ta fi ipá bá ọmọ ọdún márùndínlógún lòpọ̀.
orisiirisii - Orisirisi - July 19, 2019

Bàbá ọdún mọ́kànléláàádọ́ta fi ipá bá ọmọ ọdún márùndínlógún lòpọ̀.

Àwọn osise NAPTIP ( National Agency for the Prohibition of Trafficking in Persons) ti gbe baba odun mokanlelaaadota, onisiro ni ile iwe Government Secondary School Dangara, Abaji-Abuja, leyn ti won fi esun kan pe omo fun omo odun marundinlogun ni oogun, o fi ipa ba lopo, bee si ni o fun loyun.

Arakunrin naa, Luke Gabriql Ekundayo, lati Ilorin, ipinle Kwara, ni oluso omo naa, o ma n lo si ile re fun isimi ranpe. Omo naa je olodun keta ni secondary giga (SS3). O se aare ni ile Ogbeni Ekundayo, leyin ti o si lo oogun ti arakunrin naa fun, o sun lo. Nigba ti o ta ji ni o ri ojo lara re, ko si fura pe oluso re ti mama mama re faa le lowo pe se aburu si oun.

Arakunrin naa si deruba omo naa ti o je omo oru kan oati maa ba oun ni asepo, aijebe oun ma so fun awon ti n san owo ile iwe re pe ki won ma san an mo. O si n ba omo naa ni asepo titi to fi loyun.

Adari NAPTIP, Dame Julie Okah-Donli, ti so pe iwa buruku gba ni arakunrin naa wu, ko si ba ofin awon mu.

O ni, gbogbo eni to ba fi ipa ba ni lopo ma a jiya ese won, NAPTIP yoo si fiya ofin je won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…