Home ÀKỌ̀TUN Algeria do̩ba Afirika

Algeria do̩ba Afirika

Iko agbaboolu orileede Algeria jawe olubori ninu idije boolu alafesegba ti odun 2019, eyi waye ni orileede Egypt.
Iko yii naa ni o na orileede Naijiria ni ami ayo Kan nibi idile naa nigba ti orileede ku merin pere.
Orileede Senega ni Algeria na ni ami ayo Kan ni eyi to so Senega di onipo keji nigba ti orileede Naijiria se ipo keta nigba ti won na orileede Tunisia.
Ipade iru boolu ti orileede Afirika yii tun di odun 2021.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo Ọrẹ …