Home iroyin Adarí NYSC ti ní òun ma ran Àgùnbánirọ̀ ti o farapa lọ́wọ́.
iroyin - òpómúléró - orisiirisii - Orisirisi - July 19, 2019

Adarí NYSC ti ní òun ma ran Àgùnbánirọ̀ ti o farapa lọ́wọ́.

Adari NYSC, Brig-Gen. Shuaibu Ibrahim, ti se ileri ni ojo Wednesday fun ise, owo ike meji(limbs) ati iranlowo fun Nurudeen Tahir, agunbaniro fi o farapa ninu ijamba oko leyin ti o kuro ni kampu ni Jalingo, ipinle Taraba.

Ibrahim, ti o se ileri nigba ti o lo ki Tahir ati awon agunbaniro miiran ni Federal Medical Centre, Jalingo, ti ni iranlowo awon agunbaniro se pataki si awon.

NYSC ti Taraba ti koko gbe Tahir lo so Kano, amo o ni Taraba ni oun ti fe sin ile baba oun pe ki won gbe oun lo si Mambilla Plateau.

Leyin tiawon 2019 Batch ‘B’ Stream I se tan ni kampu ni ojo Monday 8th, July, 2019. Tahir omo Gwarzo LGA ni Kano ati awon agunbaniro mejidinlogun miiran ni ijamba oko nigba ti won lo si ibi ise ti won pin onikaluku si ni Sardauna Local Government Area. Okan ninu won ku, awon iyoku si farapa gan.

Adari NYSC ti so won won ati awon molebi won pe awon ma a se itoju, gbogbo owo ti won ma na, awon ma pese re. O si ni won ti n seto owo ike fun Muradeen ti o padanu owo re mejeji ninu isele naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…