Home Entertainment Timi Dakolo ti fèsì sí àwọn CAN.
Entertainment - orisiirisii - Orisirisi - July 17, 2019

Timi Dakolo ti fèsì sí àwọn CAN.

Timi Dakolo ti fesi si awon gbolohun ti CAN fi kale, leyin ti won fesi pe awon o ran awon eeyan lo si fi atileyin han si Pasito Biodun Fatoyinbo ti Commonwealth of Zion Assembly (COZA) ni ojo Sunday ti o koja.

Bi o tile je pe a ri fideo ti o fi Alaga CAN Abuja, Rev. jonah Samson ati igbakeji re, Rev.Isreal Akanji, nibi ti won ti n fi atileyin han fun Pasito Biodun ti Arabinrin Bisola Dakolo ati arabinrin miiran fi esun ifipabalopo kan. Sibe CAN ti so pe awon o mo nnkankan nipa fideo ti ofi awon osise won han nibi ti won n fi atileyin han si Pasito COZA.

Timi Dakolo si ti fesi si oro naa, o ni” OOTO LO MA N JARE”.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…