Home Entertainment Pásítọ̀ tí ń gbàdúrà fún àwọn aláìsàn ni ẹni tí àìsàn náà kọ́kọ́ pa.
Entertainment - orisiirisii - Orisirisi - July 17, 2019

Pásítọ̀ tí ń gbàdúrà fún àwọn aláìsàn ni ẹni tí àìsàn náà kọ́kọ́ pa.

Eni akoko ti o ni aarun ebola ni Goma, ti o je ilu to tobi ju ni orile ede Congo ti je olorun nipe, leyin ojo die ti o ko aarun ebola.

Awon DRC ni pasito naa ko aarun naa leyin ti o lo si Butembo, okan lara ibi ti won n ko awon alarun ebola si, ki o to wo oko lo si Goma. Pasito naa ti lo waasu ni ile ijosan bii mefa, ti o si gbowo le awon ti won ni aarun naa.

Ninu ipade nipa aarun ebola ni Gomina North Kivu province, Carly Nzanzu ti so pe eni akoko tí ó kú latari aarun naa ku ninu oko nigba ti won n gbe lo si ile iwosan ni Butembi lojo Monday lati lo gba itoju.

Awon osise ilera ti ri awon bi i ogota ti pasito naa ti fara kan leyin ti o ko aarun naa, won si ti fun won ni awon oogun aarun naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…