Díẹ̀ lára ilé bàbá Davido tí múná.
Ile baba Davido, Adedeji Adeleke, ti o wa ni Esther Adeleke street ni Lekki, ipinle Eko ti jona ni oni July 16. Gege bi eni ti naa waye loju re so, o ni nnkan bi aho kan osan ni ina naa bere lati ori ile ti owa ni aja ile naa.
Awon pana pana tete de ibe, won si pa ina naa ki o to bere si ni jo kaakiri ile naa. Enikeni o si farapa latari ina naa.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…