Àwọn Òṣìṣẹ́ ìjọba yóò bẹ̀rẹ̀ si ní gba 30,000naira gẹ́gẹ́ bí owó oṣù.
Aare Buhari ti fowo si ki awon osise ijoba ma a gba 30,000naira gege bi owo osu, eyi ni yoo si je owo oau ti o kere ju.
Alaga National Salaries, Invome ati Wages Commission, Richard Egbule lo so eyi ninunioade nigba ti o n soro nipa owo osu looni Tuesday July 16.
Gege bi o se, o ni igba ti won ma beere si ninsan owo naa wa lowo ofisi Accountant-General, wonnsi ma wo igba ti Aare towo bo iwe lati san owo naa.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…