Home orisiirisii Arákùnrin tó ni ilé tí ó wó ní Jos ti pàdánù àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ̀.
orisiirisii - Orisirisi - July 17, 2019

Arákùnrin tó ni ilé tí ó wó ní Jos ti pàdánù àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ̀.

Onisowo gbajumo ni Jos, Alhaji Rufai Nalele, ti o ni ile oloke meta ti o wo ni Jos, ipinle Plateau ti padanu awon molebi ri, iyawo re kekere ti oyun wa ninu re, Rukayat Salisu Nalele, omo re okunrin, omo re obinrin Amina, omo omo re obinrin Maryam ati baba re Alhaji Kabiru Nalele.

Won se adura fun awon olooogbe naa ni ojo Tuesday, Chief Imam Jos Central Mosque, Sheikh Lawal Adam lo se adari adura naa. Leyin naa ni won lo sin won si Zaria road burial ground ni Jos.

Ile oloke meta naa ti o je ile gbigbe ati ofisi oloogun oyinbo, won ni ojo Monday July 15.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…