Home orisiirisii Ìkìlọ̀ nípa àwọn ọkọ̀ ajínigbé.
orisiirisii - Orisirisi - Social Good - July 16, 2019

Ìkìlọ̀ nípa àwọn ọkọ̀ ajínigbé.

Arakunrin kan n kilo fun awon ara eko pe ki won sora fun awon oko ajinigbe ni agbegbe Berger.

O ni ki awon eeyan maa sora fun awon oko sienna ni agbegbe Berger nitori oko ajinigbe ni pupo ninu won. O ni ti won ba ti gbe awon eeyan, won a wa won lo si inu igbo, won si magba gbogbo nnkan won.

O ni orisi obìnrin meta ni isele naa ti sele si pe ki awon eeyan sora.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…