Home orisiirisii Goodluck Jonathan ti lọ kí Pa Fasoranti.

Goodluck Jonathan ti lọ kí Pa Fasoranti.

Ni aaro oni, aare ana Goodluck Jonathan ti lo ki olori afenifere, Reuben Fasoranti, ni Akure, Ondo, won ni nibe lo ti so pe idaabo n buru si labe akoso Aare Buhari.

Bi o tile je pe won ni Jonathan o daruko Buhari, won ni o so pe ijoba to tele oun.

O ni ki ijoba wa wa ona miiran lati tako idaabobo, bee lo ni eeyan o le ma se nnkan atijo ko ma reti esi tuntun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…