Home orisiirisii Federal College of Education, Umunze ti lé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ márùn-ún.
orisiirisii - Orisirisi - July 16, 2019

Federal College of Education, Umunze ti lé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ márùn-ún.

 

Federal College of Education (Technical) Umunze, ipinle Anambra, ti le akekoo obinrin kan ni ile iwe won ti n je Anyaoha Goodness Ifeoma ati awon akekoo merin miiran fun esun pe won sise pansaga lori afefe.

Ile iwe naa se ipinu naa leyin ti Student’s Disciplinary Committee fi ejo awon akekoo naa sun, eyi waye leyin ti won ko won lo si iwaju Student’s Disciplinary Committee, ti awon akekoo naa si jewo esun ti won fi kan won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…