Home orisiirisii Èèyàn méje ti kú lẹ́yìn tí ilé wó ní Jos.
orisiirisii - Orisirisi - July 16, 2019

Èèyàn méje ti kú lẹ́yìn tí ilé wó ní Jos.

Èèyàn méje ti kú lẹ́yìn tí ilé wó ní Jos.

Eeyan meje ti ku keyin ti ile oloke meta ti wop ni Seriki road ni Jos, ipinle Plateau ni ana July 15.

Gbajumo onisegun kan ti n je Alhaji Rufai Kabiru, lo ni ile naa ti o wo ni irole ojo Monday ni ago merin.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…