Home Entertainment Ẹ má rìnrìnàjò lójú títì – Ruth Kadiri.
Entertainment - orisiirisii - Orisirisi - July 16, 2019

Ẹ má rìnrìnàjò lójú títì – Ruth Kadiri.

Gbajumo osere, Ruth Kadiri naa ti dasi awuyewuye nipa iku Funke Olakunrin, omo olori afenifere, Pa Reuben Fasoranti. O ninki awon omo Naijiria ma rìnrìnàjò loju titi.

O ni idaabobo se pataki, titi digba ti awon olopaa ati ijoba ba to sise wọn, ti gbogbo wahala yii dawoduro.

O ni; ma so pe ko le sele si ki. E jo e ma danwo. Odaaro, yoo daru fun wa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…