Home ÀKỌ̀TUN Àwọn ajínigbé ti gún figilanté ní Abuja.
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - July 16, 2019

Àwọn ajínigbé ti gún figilanté ní Abuja.

Awon ajinigbe ti ji okan lara awon iyawo Local Education Authority LEA) Secetary ti Abaji Area Council,FCT. Arabinrin Hauwa Umar Ndagi.

Awon ajinigbe naa gun arakunrin omo egbe figilante, Hussain Abako, leyin ti o gbiyanju lati gba obinrin naa lowo won.

Enikan ti n gbe ni adugbo naa ni, isele naa se ni ago mokanla koja iseju mejo ale, nigba ti awon ajinigbe naa ya wo ile ti iyawo akowe naa n gbe ni Anguwar Kekeshi ni titi Toto, Abaji.

O ni orisirisi ohun elo ija, w ó n yi yin ibon soke ni aimoye igba, ki won to gbe arabinrin naa lo.

O ni akowe LEA ni won wa wa, amo nigba ti won o ri ni won se gbe iyawo re. Ninu igbo ti won ju figilante naa si ni won ti ri, ti won si gbe lo si ike iwosan.

Okan lara awon molebi won ti so fun Daily Trust pe, won ti ba awon ajinigbe naa soro, won si n beere fun milionu naira mewaa ki won to fi arabinrin naa sile.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…