Home orisiirisii Arákùnrin kan ti ké síta lẹ́yìn tó rí pé wọ́n ń ta nǹkan tí kò yẹ.
orisiirisii - Orisirisi - Social Good - July 16, 2019

Arákùnrin kan ti ké síta lẹ́yìn tó rí pé wọ́n ń ta nǹkan tí kò yẹ.

Arakunrin kan ti ke sita leyin ti o ri pe aso efon ti oun ra ni Lekki je aso ti o ye kj won ko fun awon ara IDP camp, kii se fun tita.

@ShedamsFitness so lori twitter pe oun ra aso efon ti o ye ki won ha fun awon ara IDP camp ni ofe ni N3,750 ni soobu kan ni Lekki, bi o tile je pe won ko o si lara pe kii se fun tita.

O ni; mi lero pe o ye ki won ha aso efon yii IDP camp, kii se fun tita, mo ra a ni 3,750 naira ni soobu kan to gbajumo gan ni Lekki Phase 1!

O to bi ose kan seyin ti mo ti ra a, amo nigba ti mo tu lati so o fun omo ikoko ni mo ri lebeli ti won ko”KII SE FUN TITA” si lara, ti ko si ni gbangba ara aso naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…