Home orisiirisii Arábìnrin ní òun ṣèèṣì bá àbúrò ọkọ òun ní àṣepọ̀.
orisiirisii - Orisirisi - July 16, 2019

Arábìnrin ní òun ṣèèṣì bá àbúrò ọkọ òun ní àṣepọ̀.

Arakunrin kan ti n je Ogbenin Akande ti so fun ile ejo pe oun o fe igbeyawo odun marundinlogoji pelu iyawo oun mo.

Mrs Kudirat Ajayi so fun ile ejo pe oun sesi ba aburo oko oun ni asepo nitori pe oun ro oe oko oun ni.

O ni, oun wa ni ike ni ale ojo naa, ki aburo oko oun to wa ba oun lori ibusun oun, oun si ro pe oko oun ni nitori ni dede ago yen, ago mesan si mewaa ale ni oko oun ma n ba wa oun ni asepo. O ni leyin ti o setan ni oun to mo pe kii se oko oun.

O ni nigba ti oun bere lowo re,mo ni oko oun ti rinrin ajo ni oun se wa ba oun ni asepo. O ni oun so fun iyawo egbon oun, amo o ni ki oun ma so fun egbon oun ki o ma ba si wahala. O si fun kun pe oko oun o nifee awon omo oun bii awon omo iyawo to ku.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…