Home Entertainment Timi Dakolo àti ìyàwó rẹ̀ ń ṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọmọ wọn.
Entertainment - orisiirisii - Orisirisi - July 15, 2019

Timi Dakolo àti ìyàwó rẹ̀ ń ṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọmọ wọn.

Gbajumo akorin, Timi Dakolo ati Iyawo re, Busola Dakolo n se ayeye ojo ibi omo won obinrin ti o pe odun,eje ni ana July 14.

Lenu ojo meta yii ni awuyewuye ti n lo nipa Busola Dakolo, leyin ti o fi esun kan pasito COZA, Biodun Fatoyinbo, pe o fi ipa ba oun lopo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…