Home orisiirisii Ọta ìbọn àwọn òṣìṣẹ́ SARS ti pa agbálẹ̀ Ìpínlẹ̀ Eko.
orisiirisii - Orisirisi - July 15, 2019

Ọta ìbọn àwọn òṣìṣẹ́ SARS ti pa agbálẹ̀ Ìpínlẹ̀ Eko.

Ota ibon osise SARS ti lo ba arakurin kan, o si ti gba emi re. Isele naa waye ni Ajisegiri street ni agbegbe Palmgroove ni ipinle Eko ni aaro oni July 15.

Gege bi eni ti isele naa waye loju re se so, o ni osise SARS na n le awon ti n fa igbo, nibi ti o ti n le won ni omti yin ibon, amo ato naa o lo ba eni ti o fe yin ibon naa fun, arakunrin kan ti n se ise re lowo, ti o je ile gbigba ni ita ibon naa lo ba.

Osise SARZ na salo leyin ti isele naa waye.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…