Home orisiirisii Lẹ́yìn Ọlọ́run, Otedola ló tún kàn – Coach Super Eagles tẹ́lẹ̀, Christian Chukwu.
orisiirisii - Orisirisi - July 15, 2019

Lẹ́yìn Ọlọ́run, Otedola ló tún kàn – Coach Super Eagles tẹ́lẹ̀, Christian Chukwu.

Coach Suoer Eagles tele, Christian Chukwu, ti so pe oun o mo bi o se dupe to lowo onisowo onibilionu Femi Otedola, fun iranlowo re lati san owo itoju oun.

Chukwu ti o ni aarun jejere(prostrate cancer), ti lo se ise abi ni Wellington Hospital ni London. Otedola lo si ran an lowo lati lo fun itoju naa, o fun ni seeki aadota milionu dollar fun owo itoju. Nigba ti o de pada si Naijiria, o lo fi emi imoore han si Otedola, o si ni leyin Olorun, Otedola ni eni keji laye oun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…