Home Entertainment Ìyàwó Igbákejì Ààrẹ Yemi Osinbajo, Dolapo Osinbajo ń ṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí rẹ̀.

Ìyàwó Igbákejì Ààrẹ Yemi Osinbajo, Dolapo Osinbajo ń ṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí rẹ̀.

Dolapo Osinbajo, iyawo Igbákejì Ààrẹ Yemi, ti pe omo odun mejilelaadota lonii July 15.

O gbe aworan ojo ibi re akoko si ori instagram, o si n dupe lowo olorun fun ojo ibi naa.

O ni: Mo dupe lowo olorun fun ojo ibi miiran
. Ojo ibinmi akoko

A f’ope f’olorun
. L’okan ati l’ohun wa
. Eni s’ohun ‘yanu…..

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…