Home iroyin CAN ti fi àtìlẹ́yìn hàn fún Pásítọ̀ COZA, Bidoun Fatoyinbo.
iroyin - òpómúléró - orisiirisii - Orisirisi - July 15, 2019

CAN ti fi àtìlẹ́yìn hàn fún Pásítọ̀ COZA, Bidoun Fatoyinbo.

Awon omo Naijiria ti n fi ehonu han si awon olori Christian Association of Nigeria (CAN) ni Abuja ati North Central nitori won lo ko Commonwealth of Zion Assembly COZA ati pe won fi atileyin han fun pasito re, Biodun Fatoyinbo, laaarin esun ifipabalopo ti won fi kan an.

Nigba ti awon olori CAN naa lo si ibe, won ni awon duro ti Biodun Fatoyinbo ati COZA. Eyi ya awon omo Naijiria lenu, won si n so orisirisi oro si awon olori CAN naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…