Home Entertainment BBNaija 2019: wón ti lé Kimoprah àti Ella.

BBNaija 2019: wón ti lé Kimoprah àti Ella.

Ni ale ana July 14, won le Ella ati Kimoprah kuro ninu ile big brother.

Eyinwaye leyin ti won fi Ella, Tacha, Sir Dee, Kimoorah ati Mervy si ipo awon ti o se e se ki won lole ni ose ti o koja. Amo Ella ati Kimoprah ni o ja le lori leyin tinwon le won kuro ni ale ana.

Ella ati Kimoprah ti lo darapo mo awon meji ti won le ji ose meji seyin, Isilomo ati Avala.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…