Home Entertainment BBNaija 2019: Don jazzy ti dá sí bí wón ṣe ń lé àwọn obìnrin.
Entertainment - orisiirisii - Orisirisi - July 15, 2019

BBNaija 2019: Don jazzy ti dá sí bí wón ṣe ń lé àwọn obìnrin.

Won ti le awon obinrin meji kuro ninu ile Big brother ni ale ana, Kimoprah ati Ella ni awon ibinrin ti won le.

Lile ti won le Ella ati Kimoprah yi di je ki o pe obinrin merin ti won ti le bayii.

Don jazzy si ti dasi, o ni ‘gbogbo awon obinrin ti won le yi fi han pe awon obinrin o ki n duro ti ara won, o se ni laaanu’.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…