Home orisiirisii Akẹ́kọ̀ọ́ ni UNIBEN ti pa ara rẹ̀.
orisiirisii - Orisirisi - July 15, 2019

Akẹ́kọ̀ọ́ ni UNIBEN ti pa ara rẹ̀.

Akeoo ni yunifasiti ti Benin ti n je Ephraim, ti pa ara re ni irole ana leyin ti o fo sole lati ile oloke pupo kan.

Idi ti o fi pa ara re o ti di mimo, amo a gbo pe omo olodun keta ni eka ede geesi ni Yunifásítì ti Benin, Efo ni akekoo na, o fo bole lati B series ni Faculty of Arts.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…