Home Entertainment AFCON 2019: Nigeria ti já nínú ìdíje naa.

AFCON 2019: Nigeria ti já nínú ìdíje naa.

Nigeria ti ja ninu Africa Cup of Nations 2019, leyin ti Algeria naa won ni 2-1 ni semi finals ti won gba ni Cairo International Stadium ni ojo Sunday July 14.

Awon super eagles yoo dojuko Tunisia lati ja fun ipo keta ni ono Wednesday July 17.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…