Òfin ò gbọ́dọ̀ jẹ́ kí àwọn tí ń fi ipá báni lòpọ̀ lọ – Zahra Buhari.
Omo aare Buhari, Zahra Buhari-Indimi naa ti dasi awuyewuye ti n lo lowo ifipabalopo.
O ni ofin o gbodo je ki awon ti n fi ipa bani lopo lo lasan, o ni ko ye ki won je ara awujo.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…