Home iroyin Igbákejì Ààrẹ Yemi Osinbajo ti lọ kí olórí Afẹ́nifẹ́re tí wón pa ọmọ rẹ̀.
iroyin - òpómúléró - orisiirisii - Orisirisi - July 14, 2019

Igbákejì Ààrẹ Yemi Osinbajo ti lọ kí olórí Afẹ́nifẹ́re tí wón pa ọmọ rẹ̀.

Igbakeji Aare Yemi Osinbajo ti lo ki olori afenifere, Oloye Reuben Fasoranti, ti awon ole pa omo re obinrin, Arabinrin Funke Olakunrin, ni titi Benin/Ore expressway ni ojo Friday July 12.

Osinbajo ati Gomina ipinle Ondo, Rotimi Akeredolu ni won jo lo si ile Fasoranti lati ba kedun iku omo re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…