Home Entertainment Àwòrán láti ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Rita Dominic.

Àwòrán láti ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Rita Dominic.

Gbajumo osere, Rita Dominic se ayeye ojo ibi re ni ana ojo Satide July 13 ni Eko.

O pe awon ore re bi i Toke Makinwa, Ini Edo, Omotola Jalade-Ekeinde, Kate Henshaw, D’banj, Uche Jombo ati bee bee lo sibi ajoyo ayeye naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…