Home orisiirisii Àwọn ọlọ́pàá ti mú àwọn mọ́kànlá tí wón lọ́wọ́ sí ikú ọrẹ́ wọn.
orisiirisii - Orisirisi - July 14, 2019

Àwọn ọlọ́pàá ti mú àwọn mọ́kànlá tí wón lọ́wọ́ sí ikú ọrẹ́ wọn.

Awon olopaa Turkish Cypriot ti mu awon ore mokanla ni ojo Thursday, Juky 11, won lero pe won lowo ninu iku ore won Obasanjo Adeola Owoyale, akekoo ni Cyprus International University.

Iwadii fi han pe awon ju oku Obasanjo si eyin oko re, leyin ti won lati oke keta ile ti awon olopaa lo si isale nitori gbese. Awon olopaa ri eje ati awọsọwọ(gloves) ni ibi ti isele naa ti se.

Won fi irinse to fin je nkan se Obasanjo lese ki won to ju u si isale, leyin naa ni won gbe oku re si eyin omo re, ti won si wa a lo si oki akitan, ki won to ri leyin ojo mejo.

Eni ti isele naa se loju re ni, ile naa ni ibi ti won ti ri Obasanjo gbeyin ki o to pade iku.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…