Home orisiirisii Arákùnrin ti lu ọmọ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ṣeléṣe nítorí ó jalè.
orisiirisii - Orisirisi - July 14, 2019

Arákùnrin ti lu ọmọ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ṣeléṣe nítorí ó jalè.

Arakunrin kan ti lu omo egbon re slese nitori omo naa jale. Oruko omo naa ni Abdul Isa omkoodun merinla, won n gbe ni gangare metropolis of Jos North LGA ni ipinle Plateau. Arakunrin naa lu omo naa nitori o ji egberun meta naira lowo ara ile won.

Gege bi Amama Benedict to gbe isele naa si ori instagram se so, o ni omo oru kan ni omo naa, odo aburo bab re ni o n gbe, bee si ni omo naa o lo si ile iwe ri. O ni won pada ba owo naa lowo omo naa, won si ko fun eni to ni i. Amo abuto baba re ti lu u gidi gan debi pe won ni lati ran oju omo naa.

O ni ona ti arakunrin naa fi le ba omo naa wi po, pe lulu naa ti poju, iwa ika si ni o ka iwa yii si. O ni arakunrin naa ti wa ni ago olopaa, won si n toju omo naa lowo ni ile iwosan.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…