Home orisiirisii Ìyàwó ti da omi gbóná sí ọkọ rẹ̀ lára.
orisiirisii - Orisirisi - July 13, 2019

Ìyàwó ti da omi gbóná sí ọkọ rẹ̀ lára.

Iyawo arakunfin kan ti o je oluko ni ile iwe Kano State Primary ti da omi gbona si lara nitori o fe fe iyawo keji.

Oko naa ti o n je Mallam Aliyu Ibrahim Fayan-Fayan ti fun iyawo naa ni owo ebe latinfi ra nnkan fun ara re nitori oun fe fe iyawo keji. Ni ale ojo Thursday ni nnkan bi ago mewa ale nibi ti oko ti gbo redio ni iyawo re ti da omi gbona si oju ara oko re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…